EKO AKET E. - ir.library.ui.edu.ng

10
mmM EKO AKET E. I WE I ROHIN OSOSE. Vo l 1. No 22, SATURDAY, DECEMBER 9, 1922. Foukpence £ ditor & Proprietor ADEOYK DEN IGA, Office: 24, Williams Street, P.O. Box 2Sf i, Lagos, Nigeria. nl Nigeria. 6/6d. GBOHUN-GBOHUN. 1YAWO DtTN L’ 9 §INGIfJ. Olobo ta wa pe Oji^-Qlyrun Johnny Bobbin Williams, ti Ijo Baptist agba npete ati gbe omidan VIRGINIA KljlKE, Ifa-nfanu A rchdeacon ati Mrs. N. Johnson olbgbe, ni iyawo ni 039 kejila >>• ' 1 JQ BROTHERHOOD N$E BI ARlRA. Ijo Brotherhood ti Eko npete ati se Is in Isyji lati 019 ketadi-logun- o?u yi titi ft d& ojo Keresimesi, nigbati nwpn yio'fi Isin IW e JJari-riL Ki Baba m' 9]^ r< 5 . OMI TITUN, EJA TITUN. A gb? pe Igbimp Ijoba eyiti. Goniina CLIFFORD Oln-ola fi ffc. 919 s? niuu Ile-ajy Tgbimo Qba, ti w) 20 o?ii March ti o kyja, yio di dida sil$ ninu c?il January ydun t’o mb«). Gyg? bi o ti $ pe yoda fun ilu Eko lati yan enia meta ti yip. ?oju ry r Jgbin i pe awpn aril ilu yio jf gin si i?y ribiribi yi, nigbati asiko bii tti A pi yro tian-tian lati S9 si ohun yi, ti a ?eku di “ ojo niiran Vtf^re.’' . _____ KANO 1LE IGARA. Thin pup<> kan ni lati Kano wa fun 199-ofe li PUP9 awyn Gambari n?e nibe, a s,. pa bi ilf M ti att. u di ki otokuklku enia « . fru-m fun idagiri awon 9S9I9 loru 9P9> 9P9 > le ni a g'b^ Pe aw9n ™a-so-ndoki

Transcript of EKO AKET E. - ir.library.ui.edu.ng

Page 1: EKO AKET E. - ir.library.ui.edu.ng

mmMEKO AKET E.

I W E I R O H I N O S O S E .

V o l 1. No 22, SATURDAY, DECEMBER 9 , 1922. Foukpence

£ ditor & ProprietorADEOYK DEN IGA,

Office: 24, Williams Street, P.O. Box 2Sf i,

Lagos, Nigeria.

nl Nigeria.

6/6d.

G B O H U N -G B O H U N .

1YAWO DtTN L’ 9 §INGIfJ.Olobo ta wa pe Oji^-Qlyrun Johnny B obbin Williams,

ti Ijo Baptist agba npete ati gbe omidan VIRGINIA KljlKE, Ifa-nfanu A rchdeacon ati Mrs. N. Johnson olbgbe, ni iyawo ni 039 kejila

>>• • '1JQ BROTHERHOOD N$E BI ARlRA.

Ijo Brotherhood ti Eko npete ati se Is in Isyji lati 019 ketadi-logun- o?u yi titi ft d& ojo Keresimesi, nigbati nwpn yio'fi Isin I W e JJari-riL

Ki Baba m' 9] r<5.

OMI TITUN, EJA TITUN.A gb? pe Igbimp Ijoba eyiti. Goniina CLIFFORD Oln-ola fi ffc.

919 s? niuu Ile-ajy Tgbimo Qba, ti w) 20 o?ii March ti o kyja, yio di dida sil$ ninu c?il January ydun t’o mb«). Gyg? bi o ti $ pe yoda fun ilu Eko lati yan enia meta ti yip. ?oju ry r Jgbin

i pe awpn aril ilu yio jf gin si i?y ribiribi yi, nigbati asiko bii tti A pi yro tian-tian lati S9 si ohun yi, ti a ?eku di “ ojo niiranVtf^re.’' . _____

KANO 1LE IGARA.Thin pup<> kan ni lati Kano wa fun 199-ofe li PUP9 awyn Gambari

n?e nibe, a s,. pa bi ilf M ti att. u di ki otokuklku enia « . fru-m fun idagiri awon 9S9I9 loru 9P9>9P9 >le ni a g'b Pe aw9n ™a-so-ndoki

Page 2: EKO AKET E. - ir.library.ui.edu.ng

yi kd; a wipe n w ^ 'aje jamba yi lai bikita, ti mvpn si nfy df onile mp'le: ti ihin yi ba ri b§, a ke si Ijpba ki o mil ijai gba aw^ii enia ti o wa ninu ewu bayi ni ilu aw9n "9m9-gba’ja-ibinu.”

QBA L’ O T EH IN ERIN F<,)N!Jniti o ba ka Iwe-irohin Ij9ba, ti pjtf

23 osu ti o k9ja yio ri i pe gbogbo owd-otit$ takada, bi emi ni lwe-yiyawd, Iwe-adehiin, " Ganrandi ” ati aw9n iwe ba\V9nni ni Ii9ba bu owe si patapata. O si ti di ofin nisisiyi.

GBA W ERE NG O GBA WERE.A tun $e er6 Ijiyiin miran ni Thursday

•$se yi ni Gbangan Grammar School : ohun ti a fi se ijiyan ni pe “ Ere ti awpn Ile-iwe Giga nse lemolemd nisisiyi ko 4119 suna."

E r i c : 0 . Mo o r e , Amoftn ati 919k ati 9gbeni S. A. Fa w eh in m i 9kan ninu aw9n oluk9 ile-iwe na li o jp tako ara wyn. lie kun biba

J? k 0 e w u 9 K 0 -A ki -Eni-^wp M. S. Co l e , “ kabi)'’

lati Ilu-oyinbo ti ,p ti lo lati osu karun sehin ogbeni na bit oko Abinsi “ ayara- bi-aya ” d6 ni pj$ Wednesday dsy ti o kyja.

QRQ QM9 JA-NTO-JA-NTO!!!A gbp pe ni Ipade ti a pe fun fifi aw9n

^mp-pwp ban ( Baby shoiv) ni Ile-iwe Ita Tinubu, ni Wednesday ojo 29 osu ti 0 koja, nigbati a fi n?e (isp-llera, ko si Abiamo kan ti o gb<£ 9109 ri) ypju.

E Y 1 NK()?Bi pgbpnt kan, ak9we ni Ile-ipin'we

( Post Office) nibi, ti o nj»- Wa l te r L isk • ti 9 99 gba owd-osu ti o koja owd na jy ptfnwim mejidi-logun (£ 18 ) ti 0 si fi si ibi kan nibi iyp wpn, byni o fykb: ki a

ma tun sp ti idamii ti ini 6fo ojiji fa le muwa, pelupelu ninu eyiti ara awy!' 9lomiran gbekan fun aisi owd ni'lu nisisiyi

A ba ogbeni na dard. :1ii

MAM M Y RE ’LE O, ILE L’O T.9 KO §INA!H k

A b a Bishop Ho w e l l s , ati aw9n fa ri) kydiin pfp ti o fib wph ni Friday fa] ti o k9ja nipase iku iya Bishop na, tj 0 pele ni Abeokuta.

K ’ O luw a fi i s' afefp rere.

"IT 9 IBILE N§E ’HUN ARA!!“ gNI A PETE-PERO K’ A S' QWO R$ DE

ILI?. NI PELE LI O NPELE SI I." |O to alcoko nisisiyi ti o yy ki awa enia dudu ;

1119 daju pe“ agbajp pwp ni a nfi sp aiya,” ati pe ! hi a ba tu pwo ka, a o $ubu, ki isi ye in imp las,in i nikan, $ugbpn lifihan ninu iwa \va pylu. Mo je - ori rere I'psy t'o kpja, mo ri Ivve-ipe kan gba ■ lati Qdp akpwe “ Idapp yi;by akprin Ijp Ihily’t ( African Church Choir Union) pe ki ng \ya ba , wpn wo Iran ranpy kan ni Boieltn Davies Sch oh | room ni pjp kyrin oyu November, bi a fi fi yw? : ?ere iori cln.ru. Nko ka a si nkankan, mp fyr? ; le wipe, ldni iba waniliy? Irohin koto atojubai Nigbati mo de iby ipyty pa igba ni. 0 to ohun - ti a le ko ara wa lp si jjlhingbyti s i; Aluduru I jo ; Bytyl. 9 g b y n i R. O. Taylor " A-f pwp-yp-lon duru ” li han wa bi a ti gba igi loju ti sprp ?n« p ry. Ko to ya ko to ofy, bi mo sanwo igbaduii i na ko le to by, nigbati awpn omidan. olohun ’yj ; t ’ynu b’orin ti Wuudia F. Olumide Iyr{ : f orin jy k* a lala pe a wa ni Paradise, 0 daft ynif ; ko ma daky mo. Wundia T. Ipinlaiye ati oluratfi ; lpwci aluduru Bytyl pgbyxu A. Abpyade Cdl wipe, ki ti ynikim I9 wa bi joko si nttori " ynikail t ki jy awa de ” ninu orin ajumpko enia meji \vuadi| ; E. Oriade ni on gbe omiran de. OlubOf] gbogbo ry bi yyin meji ba sure la le my olcaa tjd .:. le ya, nigbati pgbyni Cole tun tynubp oriai ily wa, o dabi ki a ma ly mp akptunkp ni, a S li awo wo ti Baba ygby yi (yni-pwp E. p A kip la, ti $ajo sily fun won pari ry. A si « ; anfani ati gbp ninu ory ti Baba ygby yi sp wipe, a da ygby yi sily niwpn pdun lcyrin sybin fuu ire awyn ygby akprin ni gbogbo Ijo enia dudu, ki irypp le wa larin awpn aluduru ati akprin w 1 a le tun orin ily wa ?eki a si ma fy lati fib*« pe *' tyni ni tyni akisa ile ina. Egby yi »

EKO AKETE [ Dbosmbjb 9 '

Page 3: EKO AKET E. - ir.library.ui.edu.ng
Page 4: EKO AKET E. - ir.library.ui.edu.ng

1 tt'lvc. ' ~T4KT T K Dkcjbmbbi; 9 ]

E K O A K E T E .

E ko, Saturday December, 9, 1922.

J.E K 1 KNITI 0 RO PE ON DURO

$QRA, KI 0 MA BA A $UBU.

Koke p’ ohun m awolco lenu nigbati thin kan ni nibi pe Adaj«,» Sir F. A. VENDER MEULEN, ti o io lati ibi fun 9jd dida ni Ab^okuta, ju 9gb?ni JOHN Ol.AWUNMI G e o r g e , Onida-jo Kotu 9019-ibi I9 ti Ake s' ewon ndun marfin, nigbati o da a l bi ^9 ti a li sun u, pe o jo “ riba ” nipo i?? r$ ni akoko kan. Dajudaju iru ohun ti 0 elt? yi ko le $e ki o ma mu otukuluku

enia dudu, pelupelu awa Yoruba apa ibi wariri, ki o si dojuti ni fun iyofjuti si aw9n elomiran ti o le mu \iv9n wipe ‘ ‘ ko si bi a ti ma ?e Ifa ti ko ni hu ’wa ekur9,’' eyini ni pe pupo ninu wa ti o wa ni ipo pataki ki sai bu lu awa to ku ti iwa-aiijododo iruf? aw9n be ba di hihan, tobe ti o fi je pe oluwa ri; tun di ^niti a nrdmu lati ba ro ^9 999 ha. §i?ubu arakunrin wa yi ya ni tynu I9P9I9P9, nigbati a ha yakiyesi iye 9dun ti o ti wa lenu i?9 Adaj? na, ti o nltr si bi odun ni9kandi-logun.

Ti a ba ni ipo wo li o ni 9la, $yb ati ib9W9-fun ti o si tun lewu ju ipo Onidaj9 ly, nitori idanwo ti o wa ninu r$, ti o si y? ki ejniti a fi sinu b? ma yera fun I9P9I9P9 ati nigbagbogbo : ipo Adajo ni, Irufy itiju ti ose 9gbeni yi muwa ko le ?e ko ma je idina fun igb^kele ti a ti nni si aw9n ^lomiran ti o wa ni ipo giga bi iru eyi. A m9 pe eru kan li o nmu ni bu igba 9m ; sib^sibe, a dupe pe nkan ko baj<? tob? ki a ma fi ri pup9 ninu aw9n ara wa miran ti o wa ni ipo nla ninu Iije-pba tabi I?9 ilu, ti nw9n ko ti aye sil? fun 999- idojutini kan lati le m9 W9n. Adura wa ni pe k irufe awon bayi ma i-tai ma p9 siwaju ati siwaju, nitoripe aw9n bb li o nj6 j iri ati igberaga awa to ku.

$ jij ki a fi ti arakunrin wa yi k’ ogbyn pc ipokipo ti a ba pb wa si, ki a sa pa l9san-loru, pelu adura ati awe ki a masfe baje ninu r$.

Ijlwe, a tanma pe ohun miran ti o nkoba •, aw9nti o wa ni ipo giga bi irufe eyi ni igbagbera ; eyi si ti i?e 9 ^ 9 enia ttyf. ■ _j iwa “ Awa li a wa nib?” “ Tani nsp to nso?” ko pe ja ni til , ayasebi oluwa ba “ kamba ” ara r$, ti ko si fi iiye fun ■ erokero lati ba a ni ifje j9-

0t9t9 9l9gb9n kan— SOLOMON— H 0 « so pe “ Oruk9 rere san ju 9P9I9P9 or$ lo.” | Yio si j ohun ti o dara, ti t’ olori t’ desi • wa ba nfi eyi S9kan riigbakugba, nitori : nipa be ni a le fi ni ireti ati se gudugudu- j nieje fun ara wa, fun Qba wa, ati pilpa' j fun il9siwaju iran wa.

A kedun ohun ti o ijele yi, a si 019 pe yio j9 adura gbogbo wa pe ki a md tun \ ri ii$nu bayi my.

A ko sa le ma pe ni li olb, ki a ma gbb 9m9*9ran jd !!!

FUN AWQN AGAN TI NTQRQ QMQ LQDQ QLQRUN.

Omo roj.0 wa lpru.i,Ka le ri un gbe pgn ka ri un ro,K’oxno kekere jojolo j’alejo ko wa s’aiye

Agan nw‘ pmp pon <?OniQbod ’Omp to d Omp ko ?owon lpdp Qlprun Agan ko ke p’ Qlgn n ogo f’omo. o

M FUN AWQN ENITI Agg?? FI SINU ISIN IGBAGBQ.

A?iri isin wa ni£ni to ba gbagbp iyyn a yege.Awaraaridi o*p Ogbpn mi' o to la de Ka li we ti Qba to da mi

iwariri mo ki wy ododo Qba;Jy ki anu R9 gbe ile miEmi ma gbagbo tpkan-tokan miBibeli mimo oitun ti mo lea ninu r? o.

Page 5: EKO AKET E. - ir.library.ui.edu.ng

- .. ■ . —

.:

Page 6: EKO AKET E. - ir.library.ui.edu.ng
Page 7: EKO AKET E. - ir.library.ui.edu.ng

December 9 J if/£r<U Q * ’

C L I M A X

World’s wonder hair beautifier for

Will straighten the m o st stubborn, coarse, or kinky hair in dive minutes, make hair lustre and silky, without the least bit grease, absolutely harmless.

Sophias cream brown Pomade known as a national hair remedy which feeds, nourishes a n d beautifies the hair, will eradicate dandruff, grow your hair long, lustrous, soft and Huffy for women and men ; Also assorted kinds of pomade and toilet soap in stock.

Dtpo Tunde, & Co.,P. O. Box 335,37, Aji$omo Street,

Lagos, Nigeria.

T he Brotherhood Christian Church.Revival Meetings ami Harvest

Thanks-giving Sendee December 17 to December 24, 1922

1 L U P E S I H A L L .Addresses by

Pastor A. Adedeji Isola, F B.P.I.,{ Fellow, British Psychological Institute )

Founder and Superintendent

Notel. Special Hymn Sheets will be sold at 3d

a copy at the Gate.a. Silver Collection every evening to defray

3. ALL AKE CORDIALLY INVITED.

AMOS l COLE,Parish Secretary•

t>gb?ni ARNOLD SCHLE-ilNOER 0x130woNI Hamburg

Yi o tete bojuto iwe ti p bakp si i, ti e ba «t A

£.m pnikpui. . ? Oja lot

The very Books you need I !General knowledge Test papers 1/.Ley to above JiReady's precis and precis writing T, , „ , with key 3/6lodes Essays and how to write them 2/9 Dixon s English Idioms ,, 2/6Nancanow's "Notes in Hygienew ]/«

The “ O R A ” Book Syndicate,(P.O. Box 17S)

33, Obun Eko Street, Lagos.

BUTTEP NYAJU!P kan ti o na Butter

“ MAGARINE” Qlpja'Agba Ayinrin

npe 1

liKl»gtaeni,-------------- «„«. ,u„oOyinbo Oni$o\vo,STANDARD COMPANY OF NIGERIA LTD

Ni I bode lailai (Custom Street) L’Eko $ile kan pere ni panu kpkau ; o ?e anfani ti a bo

ko ni giri. Qja na pp to lyppp, 5ugbpD bp lo si

■> ra tirp nibp, bi bpkp, afar

impotent suffering from sc

pills and set instant relief, tt makes a man a man

remedy for female Neurasthenia. "Disturbed menstruation, sierlity, etc., etc. Its effect is sore and permanent, in bottle of 50 pills 5/- in bottle of 100 pills 7/- are you a sufferer of that trouble­some Asthma ? Why dpnt you use Asthamacid and get rid of it at once, in bottle 5/6 These medicines are German preparations and always.

Page 8: EKO AKET E. - ir.library.ui.edu.ng

kKcT a k h t r [ DRORMBIft 9

P reachers for To-m orrow .AWQN ONIWASU QLA.

6.30— 7.30 8.30—9.307.30— 8.30 9.30—10.30.

( Evening.)Masses /Benediction) Isin Ibukuti.

4-45—5-30 6.45-7.30.St. Michael’s ( Lafiaji.)

Morning. 7 a.m —8 a.in. 8.30 a.in.—9.30 a.nEvbnning. 5.45—6,30 p

A N o L I C Ar Time.

9 a.m.—Christ Church 6.30 p.m.9 a.m.—St. Paul’s ( Breadfruit)

Rev. James Pears

6.30 p4 p.m. (Confirmation Service)

Rt. Rev. Bisjsop Ohiwplc 9 a m. & 4 p.m.-St. Peter's (Alapako) Rev. J. A. Cole 9 a.m. & 6.30 p.m.— Holy Trinity (Ebute Ero)

9 a.m.—St. David’s (Jordan)* Rev J. A. Leigh

10.30 a.n 7 p.m.

7 £■ »>•.— Ereko ’

.—Olowogbow

.— Qbun Eko

Rev. A. N. Cole Rev. S. A. Pearce Bro. S. A Stowe Rev. D. A. Beckley

9 a.m.—Bethel Rev. E. A. Akipla6.30 p.m. Bro. J. B. Coker10.30 a.m,-African Methodist Bro. J. K. Coker

4.30 p.m. Rev. 1. E. Oyeknnle—Ararpmi Church Rev. A. A. Puddicoinbe

4 p.m. Bro. M. D. AdegboyeBBEN EZBR

9 a.m. Bro. S. M. Phillips ,

( Luther Street.)COLONIAL CHURCH. IODANJ \

A nyan A won Alufa si lie Isin yi Ipspsp.

£ §U RIGIDI BO Ml O !

Owo ti a ti ri gba

Aropp .£10 16 <f E jare' 1? ma jf ko rp nyin, .,

a jihin yi IpsQsp,— [ Ed.—E. A ]

Don’t wait the moment ok neei Provide for the time of Emergency!!

The Nigeria Labour Corporation is established! 1

is a “ City of Refuge ” for all classes of u ’ reoplc. and is open lo all to come and join.

Itprotecting the intipoints of business in all parts' of Nigeria.

unjustly treated by your employe^the Corporation will fight freely for you to,

- Corporation! j

Make no hesitation, insure interest by becoming a member.THE NIGERIA LABOUR CORPORATION, '

Write for terms (enclose stamp for reply) to51 Palm Church Street, Lagos Nigeria -

Qgbpni E R IC : JOS: W. LEWIS.Jy pniti o gba iwe-a?? Ogun pipo, o ?i “ !

Egbogi Oyinbo si 14, lta Tinubu niie Ogl1?"!:. L. Williams Ologbe. ati si 34, 1 ta Qbadina I’fil® Ogbyui na Retail lali da euia lohun lpna i$f fr- ’

I«ati Motulay de Saturday.7.30 S.m dc 12.30 p.m 2 p.m de 8 p in

Ni pjp psp lati 6.30 a.m de 8.30 a.m | Owo to ngba ko ta enia lara, p Ip bpwo, .■:

Ogun rp jire.

Page 9: EKO AKET E. - ir.library.ui.edu.ng

J)BOB.Ml!ER 0 ] EKO AKETE

STEPHEN'S <E PETE DO.)4 p.m. Very Rev. J. G. Campbell

BROTHERHOOD.7.30 a.m.— llupesi Bro. J. A. Adesanya 7 p tn. „ Prof. Deniga

J'G $E 'W9 NI!" (F A IR WARNING)Qgbyni A. W. Olukolu Onigbanjo to gba A$p

pdp ljpba Nigeria, nta ori$iri$i. pja ni Gbanjo. nile Gbanjo rp ni 2, Isalpgangan Street, I’Eko.

O si nta ile ati ilp pplu.Awpn pjp pja-tita ni iwpnyi. Monday, ati

Thursday, lagogo mpta psan. Saturday, lagogo xnpsan arp, lpspsp, O utete san owo 'pja fun cnia. Mu pja rp lp si bp.

N. V. HANDELMATTSCHAPPIJ V. H.J. F. SICK ati Awqn l£gbe.

No, 7, Ita Ibodelailai, 1’ eti Glover Memorial Hall (Customs Street,) EKO.

Awpn Oyinbo oni§owo yi nran?p Ma?ini-Aran$o 4i a npe ni VESTA NoS. 1-4 t’ plpwp ati t' plpsp ni owo to rpju, a le fi iye-owo wpn han pnikpni to ba Ip si Ile-Owo yi.

Nwpn mura tan lati $e adeluin pataki pplu pnikprii to ba fp ian?p Mejila tabi ju bp lp ninu

Awpn Oyinbo yi n$e oripinpi Ilpkp alarabara, Nwpn si nran$p ( Cement) ati panu kikple to nippn, ati pja Aljpmafp ati oripiripi pja.

Ilpkun Ile awpn Oyinbo yi ?i nigbakugba ti enia ba fp lahjp ha wpn sprp A$iri nipa Owo. Irohin

He Ita Egbogi ti M acaulay.{Macaulay’s Household Dispensary.)

ILE OWO.pJA RIRAN?? TI AW0N ¥GBIJ OYINBO C. F. HUTHCHINSON

NI ILU OYINBO.

Qgbyni S. B. Vihtura, A?oju awon Oyinbo yi mora tan lab ran,, awon' Qja bi Herbadashery eyini ni $pda, Onini, Owu-§pda alarabara, Ohun-elo awon Aranpp, ati oniraru Qja bawonni lati odp awpn Oyinbo rp ni llu Oyinbo ni owo pp p.

Qgbpni na si ni awpn Akptp (Fell) Bata Funfnn

owo wpn ko ta pnia laiya.B lo dan a wo ni Ile-Owo rp. ni Ita Tiuubu, t’ o

kojusi Kotu. 1’ Eko.

9GB1<1NI DTJRO . THOMAS.ONl$OWO PATAKI.

Ti 55, Ita Faji, l’Eko, ni oriyirisi Qja to de fun u lati Hit Germany fun tita: awpn nkan -Awo abpmafp, Cement, Akara, ati ppplppp pja miran.

E lp de ibp, Igbo-Akan ’mppa ni ohun

Bi e ba fe, p kpwe si i, A1 umber Apoti-Iwe rp hi Ile ipin iwe ( General Post Office) ni 374. Number fifi-erp manamana ba a sprp ( Telephone ) ni 243.

QGBPNI J. C. VAUGHAN.Ti Ile-Qja Sheffield nj Ita Kakawa ati Ile-Qja

“ Excelsior " r.i Ita Agdrawu. ni oniruni awpn ohun kikple fun tita ni owo pppku-pypku.

O ti tijowo Irin Ipp toripiripi lati adota odnn sehin titi di oni.

'ATARI AJANAKU ni QGBPNI na jp ninn awon'oni?owo Irin I?p ni ilu Nigeria.

QKQ tita wa ni owo pp p.

ILE EGBOGI OLODUMARE.

A nta ori$iri?i ogun llera ni Ile-pja yi, to wa ni . popo-nla (Broad Street.) 1' Eko ni owo pp p.

Awpn Ogun bi Oku, Painkiller, Ogun Inarun, p Ogun Lakuregbe, Ogun Kuruna, Ogun Aran to

dara Ogun I?da, Ogun Arpmp.

Qgbpni S. A. Q. Macaulay pniti or yi jp pniti o gba A$p ogun pipo Dispenser.) lpwp Ijpba Nigeria.

ni Ilc-Egbogi i( Certificated

? LQ DAN A WO, Ogun rp jp bi idan.

A pi ile Egbogi kan ti a npe ni Ipp Olodumarc si pja Qbun Eko ni ile kpta si Iga Oloye Aroniirp. Nibp ni a 1c ri oripiripi iwosan fun onirurn aisan,

Ibape fun Orififo, Inurirun, Bda, Inarun, Aran Kinnipa, Ikp, lpa, Qrprp, Q?p Egbogi, Egbogi. Oju, ati awpn Oniruru ti a ko le to sihin tan

Rin de bp ki o wo o. Irohin ko to afojuba.Ivvo ko tilp gbp orukp rp Hdan ?

Joshua O. Apfc; Ckajs, Alabojut*.

Page 10: EKO AKET E. - ir.library.ui.edu.ng

i a f EKO AKETE Deck,mber 9'j

A L A S E L E A T H E R F A CTO R Y.‘‘ I L E A L A W O ."

Sole-Leather tanned in a most modern style and Upper-Leather prepared in all colours, namely Black, White, R e d, Yellow and Green, are obtainable at very cheap prices.

I N D U S T R Y XAwq Bata ni pppku pyoku. Kowe §pw.9

yala ni ede Yoruba tabi ti Gesi pylu owo si:—;E. B. BEYIOKU-ALASE 108, Moloney Bridge St.

P. O. Box 368. Lagos, Nigeria. TelegramsAlawpbata, Eko.

F. B L AC K B U R N & Co.

Je awyii Oyinbo oni^owo ti mvon ni ppplppy nkan afata ti ynu nje lorisirisi fun tita. Nwpn si ni aw'911 Asp JOJO ni oni- ruru to tcte nlo ni lev

$ lp ke si won ni lle-owo wpn.

Ni 45 , Marina, L ‘. ko.

Awpn A WO ati 1FE jojo ti a sp ni *’ Macaulay m’ Oluwa in’ Qba.'’ de fun tita

lpdp Ajibabi ni 89 Ip» Apongbon I’ Ekq>,Irufp awo ati Ife yi ko wppo. ? Ip ba orire nyin

pade nibp, Kosi bo ti ri ni.

A won Ecnr. Oyineo Onisowo ti a ni»b: E. H. STEIN ARA HAMBURG.

NEGERWAti r6 18. Germany.J y ’Awpij oni?OWG ti lie enia dudu,

England ati (Germany;Nwpn si nba enia ta Qja l>i Epo tabi Ekurp ti a 1' fi ran$y si wpn si I In awpn oyinbo ( Europe}-

Ko si ewu kamcan iii lati Eko tabi ilu kiiran

Ki pnikpni toba fp ba

fi A pja-kpjb' i;.n$? si ni Nigeria

wpn oyinbo yi $owo IprGr.Qghfin Karimiiv.

Kptun tiitnQba Dpsunnm No 3,. tabi ni lbi-i v; rp (Office) nr Gpopo-nla (Broad Street, j ati xu- ■ " ibi-iii Qja pain.0 si (T01 to-nova Market Store) Wi

Wire m STK IN A FR?K;^Hani burgf°W° ^ "

G iD lG B O ! GJD1GBO ! ' HEYA.! M , '

Aw9n R E C O R D S to nkyrin lede YO RUBA pp to wpbu ni ile owo. ’

MANN POOLE & COM PANY LTD., 8, TiNUBii S q u a r e . L a g o s .' • 1

Ki la ti mj’ oku T yi’un ?Ki la ti ris* orinile Iku ?

Tutu tabi Gbigby ?Qpykuyoku si ni, wa sa eyi to wu <? ni 8, TINUBU SQUARE, LAGOS.