advaio 333

4
1, Elarowa i Elarowa ii Elarowa iii Akinsala, akinsala, akinsala, Abeni ade, abeni ade, abeni ade, Ifá mo pó, ifa mo pe o, ifa mo pe, Orunmila mo pe o, orunmila mo pe o, orunmila mo pe o, Tti were ni tekute ile, Asun parade ni ti igi aja, A biamo ki gbo ekun omo re ko mo tati were, ogbo loni ki ogbo ogba loni, ki ogba iba baba oro to kete baba ileso ni ile gbo, iba baba, iba yeye, iba oluwo, iba ojugbona, iba ara. Mo n aa ti ko omo ni ifa oju ala aju ba, ki iba ose. CANCION Adupe lowo olorun Adupe lowo olorun Orun ti asun to jiwa saye Adupe lowo ori wa Adupe lowo ori wa Orun ti asun to jiwa saye Ojumo mo ho oye le ho Ojumo mo ho oye le ho Aji awa gbo ore ore owuro ho Aji awa gbo ore ore Oruro ho 2, EMPISAR Subu lade ojire, iyeloko ojire, ojikutu, lawofun ojire, ifa aji aluk loni, afeyin ti igi akoko, awa debi ti y ogbe ko gege, tako tabo ewa, bawa ni ijoko ho, onakona ti oba san mo omikun ona kona bi omi ba san mono mi osa, emi oye emi oye lan ke mo ojo , bojo ba yo ni iwonran gbogbo aye lori, ekorere wa sin wa o, akoko eruju ekorere wa o, akoko eruju igba owa lo di fa fun awa, owa oko gi gbedu, omo oko yeye won ni ti owo ji ki ofi ori ba le ki omo ki bara apetu, owani tori kinni, owan tori k oba se ku, owa owo okumo, igbo tfa aji afori bale kion, igbo won ni tio ba ji ki ho fio ri bale ki ho, owa n tori ki ni owa ni tori ko lê ba ni ire gbogbo owaji owa ni ire gbogbo 3, I DUPE. GRACIAS Orunmila ni kaso pe, ifa ni kaso pe, oni ti omo eku ba ji ko sopé lowo Eledumare, oba adani wa ye oni ohun yo fi ona aiku han orunmila ni ka sopé, ifa ni ka sopé , oni ti omo eku baji ki osope lowo ohun Eledumare, Eledumare, ni kutukutu owuro koso lowo eledumare oni ohun yo fi ona aiku

description

ifa

Transcript of advaio 333

1, Elarowa i Elarowa ii Elarowa iii

1, Elarowa i Elarowa ii Elarowa iiiAkinsala, akinsala, akinsala,

Abeni ade, abeni ade, abeni ade,

If mo p, ifa mo pe o, ifa mo pe,

Orunmila mo pe o, orunmila mo pe o, orunmila mo pe o,

Tti were ni tekute ile,

Asun parade ni ti igi aja,

A biamo ki gbo ekun omo re ko mo tati were, ogbo loni ki ogbo ogba loni, ki ogba iba baba oro to kete baba ileso ni ile gbo, iba baba, iba yeye, iba oluwo, iba ojugbona, iba ara. Mo n aa ti ko omo ni ifa oju ala aju ba, ki iba ose.CANCION

Adupe lowo olorun

Adupe lowo olorun

Orun ti asun to jiwa sayeAdupe lowo ori wa

Adupe lowo ori wa

Orun ti asun to jiwa saye

Ojumo mo ho oye le ho

Ojumo mo ho oye le ho

Aji awa gbo ore ore owuro ho

Aji awa gbo ore ore Oruro ho

2, EMPISAR

Subu lade ojire, iyeloko ojire, ojikutu, lawofun ojire, ifa aji aluk loni, afeyin ti igi akoko, awa debi ti y ogbe ko gege, tako tabo ewa, bawa ni ijoko ho, onakona ti oba san mo omikun ona kona bi omi ba san mono mi osa, emi oye emi oye lan ke mo ojo , bojo ba yo ni iwonran gbogbo aye lori, ekorere wa sin wa o, akoko eruju ekorere wa o, akoko eruju igba owa lo di fa fun awa, owa oko gi gbedu, omo oko yeye won ni ti owo ji ki ofi ori ba le ki omo ki bara apetu, owani tori kinni, owan tori k oba se ku, owa owo okumo, igbo tfa aji afori bale kion, igbo won ni tio ba ji ki ho fio ri bale ki ho, owa n tori ki ni owa ni tori ko l ba ni ire gbogbo owaji owa ni ire gbogbo3, I DUPE. GRACIAS

Orunmila ni kaso pe, ifa ni kaso pe, oni ti omo eku ba ji ko sop lowo Eledumare, oba adani wa ye oni ohun yo fi ona aiku han orunmila ni ka sop, ifa ni ka sop , oni ti omo eku baji ki osope lowo ohun Eledumare, Eledumare, ni kutukutu owuro koso lowo eledumare oni ohun yo fi ona aiku han idin owonrin rosun asope, elawori asope orunmila asope lowore adupe ni pa ase orunmila, bara agboni regun. Ase Edumare.4, I DARINGIN ESSE. PERDONOni toki lawo ode egba, ol obu iyepe sese lawo ode ijesa okete abori bobo adi fa fun odun ela omo larogun ti o sese kanra kan ti o se ara du e ri,bara petu ni ka wa be ho, bara petu mon ti gbe be ije be de lawo olugbebe ti a bati rawo re be ni aje bebe ni igbin de omo oni ipere akoko ifa yo poro si awo ni ile yo poro si awo lona a ti oni ka lu ku wa ho. Ase5, IRIN AJO

Apalan ba atisa, adi fa fun ade, ti se yeye onilu, oni ibi o sun won lomo ohun loni, ade loni ki ode obobo loni ki opada bo ni irin ajo, ewo orisa eye keye ki fo ko fi orisoa i, bi na ba ko odi owo eni tin f ina, borun kobaranmo odi pwp olodumare, adi fa fun aina ka tin se awo lo si ilumokun won ni bi ise tohoun ayan ko ni yan, era koni rin, eni ayan bayan nikuso si inu igbo eni era barin ni kuso si a luju ona, ifa ni a lore abo re a ni sije.AES EDUMARE

6, I JUBA

Ajirawo lawo ajirawo, ajirase rase lawo, aijrase, ajirawo rase, lo di fa fun ajiraworase moyin ho, ajirawo rase awo rere, ti a ba ji ki eledumare kawe owo e ni fini, kawe esse e ni fini, kawe gbogbo ara e ni ko fin ninini, tori ara e ni edumare gbe ibi okun kun edumare ki gbe ibi eri edumare ki gbe ibi egbin orunmila eri gi alo, je ki ona re ko la fun wa O. ase7, IPABI

Aji mo bi kan ile lo di fa fun Ala moye awon, agba to ba ji to fio bi kan l ori awon adarugbo ke lese obarisa, kanna jangbon ori e abeso jingbini a di fa fun olomo, i ti jogun etan, abufun olomo i ti jogun obi, kato fie yin ti kato jogun obi, kato fie yin to jogun etan, ire gbogbo ni towo e ni igbin de omo oni ipere a koko ifa opor osawo ni l ifa ho poro sawo lona, kato feyeyin ti ka to jogun iregbogbo, ire gbogbo ni towo eni moto ki lawo moto ki moto yin lawo motoyin, motoyin bunban bolori, adi fa fun kowe oya, omo adabo oke ti n b ora kinrakin, orunmila lo de erro opo erro ofa eyan to ba fun ikin lo bi ara je so hun rere erin ke erin sese adi fa fun kowe, ti yo pa bi lafin, koko re ni, adi fa fun lan ta kun,tin lore raye eleru, baduro bawure ire awa ko sai gba, bi abere ti awure ire awa ko saigbo, bi ayoko bi awure ire wa ko saigba, alaba lasa, alamun lasa, a di fa fun orunmila tin lo re gbe kolobo ni iyawo, ba laye amon laye kolobo fie nu ara re wure, kolobo ba ni ire gbogbo amo ni ire gbogbo kolobo fenu arare wure kolobo ire kan eji kan ti aba su loni ki eledumare ba wa mun ile ase.

ASE EDUMARE

8,

1. IFA ITANIJE LEYIN IGBANA

2. IWURE LATI ENU OKUNRIN

3. IWURE LATI ENU OBINRIN

9, ORIN IPARI

Awure tan anre l baba Edumare mon ba w alo

Awure tan anre l baba Gbogbo irunmole mo ba wa alo

,, ,, ,, ,, Ejiogbe mo ba w alo,, ,, ,, ,, Oyekumeji mo ba w alo

,, ,, ,, ,, Iwori meji mo ba wa lo

,, ,, ,, ,, Odi meji mo ba wa lo

,, ,, ,, ,, Irosun meji moba wa lo

,, ,, ,, ,, Ownrn meji mo ba wa lo

,, ,, ,, ,, Obara meji mo ba wa lo,, ,, ,, ,, Oknrn meji mo ba wa lo

,, ,, ,, ,, Ogunda meji mo ba wa lo

,, ,, ,, ,, Osa meji mo ba wa lo

,, ,, ,, ,, Ika meji mo ba wa lo

,, ,, ,, ,, Ologbon meji mo ba wa lo

,, ,, ,, ,, Otura meji mo ba wa lo

,, ,, ,, ,, Irete meji mo ba wa lo

,, ,, ,, ,, Ose meji mo ba wa lo

,, ,, ,, ,, Ofun meji mo ba wa loAwure tan anre le baba Ose eleru mo ba wa lo

Awure tan anre le baba Gbogbo irun mo ba wa lo

Awure tan anre le baba Gbogbo odu mo ba wa lo

Awure tan anre le baba Eleumare mo ba wa lo.3